Jer 46:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Goke lọ si Gileadi, ki o si mu ikunra, iwọ wundia, ọmọbinrin Egipti: li asan ni iwọ o lò ọ̀pọlọpọ õgùn; ọja-imularada kò si fun ọ.

Jer 46

Jer 46:2-13