Jer 45:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ wipe, Egbé ni fun mi nisisiyi! nitori ti Oluwa ti fi ibanujẹ kún ikãnu mi; ãrẹ̀ mu mi ninu ẹ̀dun mi, emi kò si ri isimi.

Jer 45

Jer 45:2-5