Jer 44:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn lati igba ti awa ti fi sisun turari fun ayaba ọrun silẹ, ati lati da ẹbọ ohun mimu fun u, awa ti ṣalaini ohun gbogbo, a si run nipa idà ati nipa ìyan.

Jer 44

Jer 44:11-23