Jer 44:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi o bẹ̀ awọn ti ngbe Egipti wò, gẹgẹ bi emi ti jẹ Jerusalemu niya, nipa idà, nipa ìyan, ati nipa àjakalẹ-arun;

Jer 44

Jer 44:11-16