Jer 44:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli, wi pe, wò o emi doju mi kọ nyin fun ibi, ati lati ke gbogbo Juda kuro.

Jer 44

Jer 44:2-16