Jer 43:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun, ati gbogbo awọn enia, kò gbà ohùn Oluwa gbọ́, lati má gbe ilẹ Juda,

Jer 43

Jer 43:1-10