Jer 42:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni o pè Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o wà pẹlu rẹ̀, ati gbogbo awọn enia lati ẹni-kekere titi de ẹni-nla.

Jer 42

Jer 42:6-17