Jer 41:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Iṣmaeli, ọmọ Netaniah, ati awọn ọkunrin mẹwa ti nwọn wà pẹlu rẹ̀, nwọn fi idà kọlu Gedaliah, ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, nwọn si pa a, on ẹniti ọba Babeli ti fi jẹ bãlẹ lori ilẹ na.

Jer 41

Jer 41:1-3