Jer 41:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti ẹ̀ru ba wọn niwaju awọn ara Kaldea, nitoriti Iṣmaeli ọmọ Netaniah, ti pa Gedaliah, ọmọ Ahikamu ẹniti ọba Babeli fi jẹ bãlẹ ni ilẹ na.

Jer 41

Jer 41:14-18