Jer 40:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Gedaliah, ọmọ Ahikamu, sọ fun Johanani, ọmọ Karea pe, Iwọ kò gbọdọ ṣe nkan yi, nitori eke ni iwọ ṣe mọ Iṣmaeli.

Jer 40

Jer 40:15-16