Jer 4:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe li ọjọ na, li Oluwa wi, ọkàn ọba yio nù, ati ọkàn awọn ijoye: awọn alufa yio si dãmu, hà yio si ṣe awọn woli.

Jer 4

Jer 4:6-13