Jer 4:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo bojuwo, sa wò o, Karmeli di aginju, ati gbogbo ilu rẹ̀ li o wó lulẹ, niwaju Oluwa ati niwaju ibinu rẹ̀ gbigbona.

Jer 4

Jer 4:17-27