Jer 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ wi fun awọn orilẹ-ède; sa wò o, kede si Jerusalemu, pe, awọn ọluṣọ-ogun ti ilẹ jijin wá, nwọn si sọ ohùn wọn jade si ilu Juda.

Jer 4

Jer 4:11-21