Jer 4:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni a o wi fun awọn enia yi ati fun Jerusalemu pe, Ẹfũfu gbigbona lati ibi giga ni iju niha ọmọbinrin enia mi, kì iṣe lati fẹ, tabi lati fẹnù.

Jer 4

Jer 4:6-18