Jer 4:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

Israeli bi iwọ o ba yipada, li Oluwa wi, yipada sọdọ mi; ati bi iwọ o ba mu irira rẹ kuro niwaju mi, iwọ kì o si rìn kiri:

Jer 4

Jer 4:1-10