Jer 39:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mu u, ki o si bojuto o, má si ṣe e ni ibi kan; ṣugbọn gẹgẹ bi on ba ti sọ fun ọ, bẹ̃ni ki iwọ ki o ṣe fun u.

Jer 39

Jer 39:3-18