Jer 39:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati a kó Jerusalemu (li ọdun kẹsan Sedekiah, ọba Juda, li oṣu kẹwa ni Nebukadnessari, ọba Babeli, ati gbogbo ogun rẹ̀ wá si Jerusalemu, nwọn si dó tì i.

Jer 39

Jer 39:1-4