Jer 37:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibo ni awọn woli nyin ha wà nisisiyi, awọn ti nsọtẹlẹ fun nyin, wipe, Ọba Babeli kì yio wá sọdọ nyin ati si ilẹ yi?

Jer 37

Jer 37:13-21