Jer 37:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. SEDEKIAH, ọmọ Josiah si jọba ni ipo Koniah, ọmọ Jehoiakimu, ẹniti Nebukadnessari, ọba Babeli, fi jẹ ọba ni ilẹ Juda.

2. Ṣugbọn ati on, ati awọn iranṣẹ rẹ̀, ati awọn enia ilẹ na, kò fetisi ọ̀rọ Oluwa, ti o sọ nipa Jeremiah, woli.

Jer 37