Jer 36:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Baruku, ọmọ Neriah, si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti Jeremiah, woli, ti palaṣẹ fun u, lati ka ọ̀rọ Oluwa lati inu iwe ni ile Oluwa.

Jer 36

Jer 36:7-17