Jer 36:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jeremiah pè Baruku, ọmọ Neriah; Baruku si kọ lati ẹnu Jeremiah gbogbo ọ̀rọ Oluwa ti o ti sọ fun u, sori iwe-kiká na.

Jer 36

Jer 36:1-10