Jer 36:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tun mu iwe kiká miran, ki o si kọ gbogbo ọ̀rọ iṣaju sinu rẹ̀ ti o wà ninu iwe-kiká ekini, ti Jehoiakimu, ọba Juda, ti fi joná.

Jer 36

Jer 36:22-32