Jer 36:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ọdun kẹrin Jehoiakimu, ọmọ Josiah ọba Juda, li ọ̀rọ yi tọ̀ Jeremiah wá lati ọdọ Oluwa wá, wipe,

Jer 36

Jer 36:1-11