Jer 35:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni mo mu Jaasaniah, ọmọ Jeremiah, ọmọ Habasiniah, ati awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo awọn ọmọ rẹ̀, ati gbogbo ile awọn ọmọ Rekabu;

Jer 35

Jer 35:1-13