Jer 35:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa ngbe inu agọ, a si gbọran, a si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti Jonadabu, baba wa, palaṣẹ fun wa.

Jer 35

Jer 35:6-17