Jer 32:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si rà oko na lọwọ Hanameeli, ọmọ ẹ̀gbọn mi, ti o wà ni Anatoti, mo si wọ̀n owo fun u, ṣekeli meje ati ìwọn fadaka mẹwa.

Jer 32

Jer 32:1-18