Jer 32:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fun wọn li ọkàn kan, ati ọ̀na kan, ki nwọn ki o le bẹ̀ru mi li ọjọ gbogbo, fun rere wọn, ati ti awọn ọmọ wọn lẹhin wọn:

Jer 32

Jer 32:29-40