Jer 32:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ilu yi ti jẹ ohun ibinu ati irunu fun mi lati ọjọ ti nwọn ti kọ ọ wá titi di oni yi; tobẹ̃ ti emi o mu u kuro niwaju mi.

Jer 32

Jer 32:22-32