Jer 32:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, bayi li Oluwa wi, Wò o, emi o fi ilu yi le ọwọ awọn ara Kaldea, ani le ọwọ Nebukadnessari, ọba Babeli, on o si kó o:

Jer 32

Jer 32:20-36