Jer 32:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli, wipe, A o tun rà ile ati oko ati ọgba-ajara ni ilẹ yi.

Jer 32

Jer 32:7-20