Jer 31:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọjọ na ni eyi, ti awọn oluṣọ lori oke Efraimu yio kigbe pe, Ẹ dide, ẹ si jẹ ki a goke lọ si Sioni sọdọ Oluwa, Ọlọrun wa.

Jer 31

Jer 31:3-15