Jer 30:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oṣe! nitori ọjọ na tobi, tobẹ̃ ti kò si ọkan bi iru rẹ̀: o jẹ àkoko wahala fun Jakobu; sibẹ a o gbà a kuro ninu rẹ̀.

Jer 30

Jer 30:2-10