Jer 30:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wò o, afẹfẹ iji Oluwa! ibinu ti jade! afẹyika ìji yio ṣubu ni ikanra si ori oluṣe-buburu.

Jer 30

Jer 30:16-24