Jer 3:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin gbogbo wọnyi, sibẹ Juda, alarekereke arabinrin rẹ̀, kò yipada si mi tọkàntọkàn ṣugbọn li agabagebe; li Oluwa wi.

Jer 3

Jer 3:1-13