Jer 28:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jeremiah, woli, wi fun Hananiah, woli, pe, Gbọ́ nisisiyi, Hananiah; Oluwa kò rán ọ; ṣugbọn iwọ jẹ ki enia yi ki o gbẹkẹle eke.

Jer 28

Jer 28:7-17