Jer 27:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi, niti ohun-èlo ti o kù ni ile Oluwa, ati ni ile ọba Juda ati Jerusalemu.

Jer 27

Jer 27:20-22