Jer 27:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẽṣe ti ẹnyin o kú, iwọ, ati enia rẹ, nipa idà, ati ìyan, ati ajakalẹ-arun, bi Oluwa ti sọ si orilẹ-ède ti kì yio sin ọba Babeli.

Jer 27

Jer 27:9-20