Jer 26:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa wi: bi ẹnyin kì yio feti si mi lati rin ninu ofin mi, ti emi ti gbe kalẹ niwaju nyin.

Jer 26

Jer 26:1-12