Jer 26:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni ọwọ Ahikamu, ọmọ Safani mbẹ pẹlu Jeremiah, ki nwọn ki o má ba fi i le awọn enia lọwọ lati pa.

Jer 26

Jer 26:17-24