Jer 26:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ijoye Juda gbọ́ nkan wọnyi, nwọn jade lati ile ọba wá si ile Oluwa, nwọn si joko li ẹnu-ọ̀na titun ile Oluwa.

Jer 26

Jer 26:6-20