Jer 25:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, sa wò o, ibi yio jade lati orilẹ-ède de orilẹ-ède, ìji nlanla yio ru soke lati agbegbe aiye.

Jer 25

Jer 25:24-38