Jer 25:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu emi o mu ohùn inudidùn, ati ohùn ayọ, ohùn ọkọ-iyawo, ati ohùn iyawo, iro okuta ọlọ, ati imọlẹ fitila kuro lọdọ wọn.

Jer 25

Jer 25:5-17