Jer 24:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si kọju mi si wọn fun rere, emi o si mu wọn pada wá si ilẹ yi, emi o gbe wọn ró li aitun wó wọn lulẹ, emi o gbìn wọn, li aitun fà wọn tu.

Jer 24

Jer 24:3-10