Jer 24:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si rán idà, ìyan, ati ajakalẹ-arun, si ãrin wọn, titi nwọn o fi parun kuro ni ilẹ eyi ti emi fi fun wọn ati fun awọn baba wọn.

Jer 24

Jer 24:8-10