Jer 22:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Goke lọ si Lebanoni, ki o si ke, ki o si gbe ohùn rẹ soke ni Baṣani, ki o kigbe lati Abarimu, nitori a ti ṣẹ́ gbogbo olufẹ rẹ tutu,

Jer 22

Jer 22:15-25