Jer 22:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi fun Ṣallumu, ọmọ Josiah, ọba Juda, ti o jọba ni ipo Josiah, baba rẹ̀, ti o jade kuro nihin pe, On kì yio pada wá mọ.

Jer 22

Jer 22:10-21