Jer 21:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn emi o jẹ nyin niya gẹgẹ bi eso iṣe nyin, li Oluwa wi; emi o si da iná ninu igbo rẹ ki o le jo gbogbo agbegbe rẹ.

Jer 21

Jer 21:7-14