Jer 21:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi ti yi oju mi si ilu yi fun ibi, kì isi iṣe fun rere, li Oluwa wi: a o fi i le ọba Babeli lọwọ, yio fi iná kun u.

Jer 21

Jer 21:4-14