Jer 20:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Paṣuri lù Jeremiah, woli, o si kàn a li àba ti o wà ni ẹnu-ọ̀na Benjamini, ti o wà li òke ti o wà lẹba ile Oluwa.

Jer 20

Jer 20:1-5