Jer 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa wi: Aiṣedede wo li awọn baba nyin ri lọwọ mi ti nwọn lọ jina kuro lọdọ mi, ti nwọn si tẹle asan, ti nwọn si di enia asan?

Jer 2

Jer 2:1-11